Hymn 356: DURO, duro fun Jesu / Uncategorized / By b_cosmical Verse 1DURO, duro fun Jesu,Enyin om’ogun Krist’:Gbe asia Re s’ oke,A ko gbodo fe ku;Lat’ isegun de ‘segunN’ y’o ma to ogun Re;Tit’ ao segun gbogb’ ota,Ti Krist’ y’o j’ Oluwa. Verse 2Duro, duro fun Jesu,F’ eti s’ ohun ipe;Jade lo s’ oju ijaL’ oni ojo nla Re;Enyin akin ti nja funLarin ainiy’ otaN’nu ewu e ni ‘gboiyaĘ koju ‘ja s’ ota Verse 3Duro, duro fun Jesu,Duro l’ agbara Re;Ipa enia ko to,Ma gbekele tire;Di ‘hamora ‘hinrere Ma sona, ma gbadua,B’ ise tab’ ewu ba pe,Ma se alai de ‘be. Verse 4Duro, duro fun Jesu;Ija na ki y’o pe;Oni, ariwo ogun,Ola, orin ‘segun;Enit’ o ba si segun,Y’o gba ade iye;Y’o ma ba Oba OgoJoba titi lailai. Amin